THE GOSPEL THROUGH CHRISTIAN DRAMA AND FILMS

This is the official blog site of Land of God Evangelical Drama and Film Ministries (LOGEMmin.) based in Ogun State, Nigeria. Motto: Acting the Word in God's Land by Faith Contact us @ 07038568584, 08063044454. top4ever01@gmail.com

Thursday, 10 March 2022

ÀJÒ ÀRÈMABỌ̀

 


Ẹwí fún Lámọrín kódúró n'lé,

Ẹsọ fún Tàmẹ̀dù pé kó fìdí m'ágbàlá baba tó bíi lọ́mọ...


Ẹṣí i létí kóle rántí,

Ẹnà á ní pàṣán ọ̀rọ̀ ní yàrá,

Ẹgbà á n'ímọ̀ràn lọ́ọ̀dẹ̀,

Ẹjẹ́ kó mọ'rú ọṣẹ́ táyé fií ṣ'elétí ikún ọmọ,


Ẹjẹ́ kó mọ'rú ìyà tíí j'aláìgbẹ̀kọ́ bíi ti Dínà ọmọ Jákọ́bù,

Ẹni wọ́n wí fún pé kó dúró n'lé

Ẹni wọ́n kì nílọ̀ pé kó f'ìdí m'ágbàlá,

Kàkà kí Dínà tẹ́tí gbọ́'hun baba rẹ nwí,

Kàkà kó f'ìrẹ̀lẹ̀ tẹ̀lé m'ọ̀ràn òbí, 

níṣe lọ̀rẹ́ wa fò fẹ̀rẹ̀, 

t'ófẹ́ lọ f'ójú lónjẹ,


Dínà kúrò n'lé,

Ó fẹ́ lọ w'ohun ayé nṣe,

Dínà tàpá símọ̀ràn òbí,

Óṣ'ohun tí gbogbo ọmọ elétídídi nṣe,


Ó s'àpò ìyà kọ́,

Órìn'rìn àjò àrè-f'arak'ááṣá ọdẹ ayé,

Ó lọ ní kíkún, ó padà l'ófìfo!

Ó lọ l'ódindi, 

ó padà pẹ̀lú ayé àlàpà,

Ó lọ pẹ̀lú ẹ̀wú ẹ̀yẹ,

Ó padà s'ílé n'íhòhò!


Ṣékémù f'ipá gb'aṣọ ògo ìbí tí Dínà dàbo'ra!

Ah! Ìtìjú àt'ẹ̀sín dé!

Ọjà ogo Dínà di kòròfo!


Ẹbáwa já'wé gbélé jẹ́ fún gbogbo màjèsín,

Ẹf'òrí f'ìdí m'ọ́ọ̀dẹ̀ wọ́ra fún gbogbo ọ̀dọ́ ìwòyí,

Ẹní kíwọ́n yé sunlé oníle kiri


Ẹní kíwọ́n fìtẹ́lọ́rùn ṣ'ẹ̀wù àwọ̀tẹ́lẹ̀, 

kíwọ́n f'ìwà bí Ọlọ́run ṣaṣọ àmúròde,


Ẹwí fúnwọn 'pe

gbogbo ohun t'ón dán kọ́ ni wúrà

Ẹsín wọn ní gbẹ́rẹ́ ìpàkọ́ kí wọ́n le mọ̀ 'pe; ikú nbẹ nínú ọ̀pọ̀ ìkòkò tó ṣojú rekete lóde!


Ẹní kíwọ́n yé f'ira wọn w'ówó kiri,

Ẹni kíwọ́n dúró d'àsìkò t'Ólùgbàlà ti pèsè sílẹ̀ láti d'aṣọ ògo bò wọ́n,

Ẹní kíwọ́n dúró nlé bí ti Rèbékà ọmọ Betueli,

Akínkanjú ọmọ tín fetí s'óhun òbí bá sọ,

Ó gbá'jú mọ́'ṣẹ́ baba,

Of'ìrẹ̀lẹ̀ tẹ́tí s'ímọ̀ràn òbí,

Kò rìn'rìn àrèmabọ̀, 

Bẹ́ẹ̀ni kò kó sí pánpẹ́ ibi ayé dẹ fún gbogbo ọmọ elétídídi, 

Kò sọ òbí s'írònú

Kò sọ ẹbí l'órúkọ ibi


Ẹ̀bẹ̀ mi rèé sí gbogbo òbí t'ófẹ́ f'ẹ̀yìntì j'oúnjẹ́ ọmọ, 

Ẹwí fún gbogbo ọ̀dọ́bìnrin pé; Kiwọ́n dúró n'lé, 


Lórúkọ Jésù, ọmọ wa òní rìn'rìn àjò àrèmabọ̀, Àmín.🙏

#tolulopeadeoye#

Tuesday, 1 March 2022

IFE WÁ TI GBẸ

IFE WÁ TI GBẸ

Ife wá ti gbẹ Olúwa Ọlọ́run ìgbàlà wa...🍷


Ati ṣáko jìnnà kúrò nínú ìfẹ́ Rẹ, bẹ́ẹ̀ laòsì fura...🤦‍♀


Ìgbónà ọkàn fún iṣẹ́ ìjèrè ọkàn ti di ohun ìgbàgbé, ọ̀pọ̀ nínu wa sítì sùn lọ l'ójú ogun...😭


Ati sọ ohun iyebíye t'Ofún wa nù nítorí àti lówó lọ́wọ́...😭


Asọ ẹ̀bùn ìgbàlà nù nìtorí àti jéèyàn lórí èèpẹ̀...😭


Ati gbàgbé wípé ohun t'Ó torí sọwá dọmọ ni kí gbogbo ayé óle fẹ́ Ọ,

Aò rántí ìlérí ìpèsè ọ̀fẹ́ tí O ṣe fún wa...😢🤦‍♀

Tawájí Olúwa!!!


Ati fi ọ̀rọ̀ ìjèrè ọkàn tàfàlà, àfi kí O dákun gbàwá...😭🙏🙏🙏


Òùngbẹ Rẹ ngbẹ ọkàn wa Olúwa...

àní, òùngbẹ ìwọ Ọlọ́run alààyè.😭


Ati sọ gèlè nù,🙆‍♀️

fìlà lohun táa nawọ́ mú,

Ati ju fìlà sílẹ́, gèlè làńgbé kiri...

Baba àfi kO gbàwá!😭


Ife wá ti gbẹ, Olúwa wá kúnwa...🙏


Ìf'àmìòróróyàn titun l'a bèèrè, 

Ẹ̀yí tí kò l'ábùlà, bíi ti ọjọ́ Pẹ́ntíkọ́stì,

Baba dákun tu léwa l'órí...🔥🔥🔥


Bí ọkàn àgbọ̀nrín tií máa fà sí odò tí omi rẹ̀ tutù,

bẹ́ẹ̀ ni ọkàn wa ń fà sí Ọ, Ọlọrun.😭

Wá tún wa ṣe, kí O sọwá di tìRẹ l'akọ̀tun...


Afẹ́ padà sínú ìfẹ̀ àkọ́kọ́ nínu Rẹ🙏

Afẹ́ kí O dá iná ìyè Rẹ padà s'órí pẹpẹ àdúrà wa...


Afẹ́ kí O fún wa ni okun àti oore ọ̀fẹ́ láti gbààwẹ̀ àti láti gbàdúrà láìsinmi àti láì ṣàárẹ̀ nígbàgbogbo...

Afẹ́ máa ṣe àṣàrò nínú Ọ̀rọ̀ Rẹ nígbàgbogbo🙏


Tan Ìmọ́lẹ́ Rẹ kí O sì lé òkùnkùn lọ kúrò,

Ṣí wa lójú Jẹ́kí arí Ọ Olúwa,

Fi Omi ìyè Rẹ fún gbogbo ọkàn àwa tí òùngbẹ Rẹ ńgbẹ...🙏


Ṣí etí ìgbọ́ràn wa, kí ale gbọ́ ẹ̀kọ́ tí Oń kọ́ wa...

Fún wa létí ìgbọ́ràn àti àyà tí óngba Ọ̀rọ̀ Rẹ dúró...


Jẹ́kí gbogbo ayé mọ̀ wípé Ìwọ nìkan ni Olúwa láyé àti lọ́run àti wípé tìRẹ làwa nṣe...


Èyí l'ẹ̀bẹ̀ wa, Oluwa l'Órúkọ Jésù Kristi, Àmín.🙏🙏🙏


Kàn sí👇

http://landofgodministry.blogspot.com

Fún àwọn àtẹ̀jáde wa míràn.

Jésù ni Olúwa, Àmín.🙏

#tolulopeadeoye#


Friday, 8 October 2021

#Gospel #Faith MOMENT WITH ALAGBA EPISODE 13: HOW TO KEEP HOPE ALIVE

In a time like this when things are getting tougher and more discouraging and challenging, one tends to give in to hopelessness, doubt, worry and fear. The Lord in His mercy is so concerned about His children and hopes they sustain their hope and trust in Him for He is able to see them through all odds and challenges of life. Here is hope. keep it.

Thursday, 13 May 2021

'DEAR DAUGHTER' Written by Tolulope Adeoye

 Dear daughter,

Your letter dated the 14th of February arrived late in the night through our next door neighbour's daughter, Gloria. 

Her parents just moved in 3 months ago and I was so shocked when she told me you'd sent her and also made her promised never to reveal where you live to me...I must say I'm so happy that at least I could hear from you after all these years.


Daughter, I am sincerely sorry for all my negligence and carelessness. 

I was a foolish builder, sleeping while the enemy plunders my home but thanks be to God for Cecil's mother who invited me to a Women's meeting organized by Vision Carriers Intl., there I met the Lord Jesus and He turned my life around. I realized my foolishness and I embraced the loving offer of Salvation from Jesus. He forgave all my sins and ever since, He has been so faithful to me.

Since I met the Lord, daughter, I've never stopped praying for you. I've been begging God for your salvation and I'm so certain that He will save you.

See, the only place where help lies is in Christ Jesus and that's only if we will receive and accept His great offer of salvation through His blood.

God has not given up on you dear and Jesus still loves you. He's waiting for you to come to Him right now.

His hands are wide open and His ears are not shut, He is eagerly waiting for your call and we are also waiting to receive you back home!


More so, I need to let you know that your dad has returned home! God brought him back to us after all these years!


If only I had known then the Truth I now know in Christ, we wouldn't have faced all of the hardship we faced due to your father's absence in the home. God did not only bring him back to us but I'm happy to tell you that he is now saved too!


He met the Lord through a friend and the veil of sin and the devil fell off his face immediately he surrendered his life to the Lordship of Jesus Christ! He ended his relationship with the strange woman he went away with for years. We all received him with open arms the day he came back. We forgave him, your siblings and I, despite all he had done. Please, forgive him too. He has changed from the man he used to be, both to me and to your younger ones.


Just yesterday, Gloria our next door neighbour's daughter gave her life to Christ! It was beautiful seeing her beam with a peaceful smile after I and your dad prayed for her. She was the one who promised to deliver this letter to you today.

Though we didn't bother asking where you live since she has promised you not to reveal it to us. We will keep waiting and trusting God to bring you home to us.


We never stopped loving you dear and every one of us is eagerly waiting for the day you'll walk back through the door that is widely opened waiting for your return.

Your siblings have also taken it upon themselves (apart from the family prayer time) to hold intercessory prayers on your behalf in your room since your dad renovated it in preparation for your coming (you'll love it). According to him, 'the Lord that brought him back will bring you back when you are ready...'


We are ALL WAITING dear, please make no further delay. We love you but Jesus loves you more!


Once again, I am sorry for all the hurts and pains I have caused you. Please give me another chance to be the mother the Lord has called me to be to you sweetheart and I promised never to fail God again in my assignment.

Love you so much, Angel❤️❤️❤️


YOUR WAITING MUM❤️


Sunday, 14 February 2021

"DEAR MUM..."

 




    DEAR MUM,


I know you wouldn't believe all I'm going to say but I plead with you in God's Name to believe every of my words for they are true and real...


Do you remember that that year? Precisely on the 13th day of the second month...


I came home from school and you were busy in the kitchen preparing daddy's meal so you can meet up for the community women's meeting at mama Kofo's house (Do you remember now?)...


I told you I wanted to have personal talk with you then (remember?) but you simply laughed and asked me to say it there because you are very busy.

If you could remember vividly, I told you not to worry and walked into my room quietly...


The following day was 14th of February and I told you I wanted to go and visit my classmate in town...

Though you saw me dressed in that body revealing clothes yet you didn't say anything rather than your normal phrase "you children of nowadays sa..."( How I wished you had said more or even do something)

You were so busy with your discussion with our neighbor's second wife who came to discuss her rival's daughter's case with you...

You counselled her on how to be a good mother to her step-daughter while you never had time for me...(How I wished you were dead too like our neighbour's first wife so that I could have a step mother like aunt Cecil who would do anything to ensure I was properly raised...)


I wished you had stopped to search my bag that day (I had extra clothes and make-up kit etc. in the bag) ...😢


I wished you had cautioned me 😢


I wished you had had time for me like aunt Cecil had for Fortress...


I saw her with her step -daughter eating Ice-cream that afternoon at the City Fair Mall while I was with my friends, waiting at the mall for the vehicle that took us to the Beach Resort where we did all manner of things together😭


Mum, it's been years now...

And I'm reaping the results of that year😢


Mum, do you know that the events of that single day launched me into a terrible sexual prison...😭


I never knew I was in for trouble when I started having string urge for sex whenever I see a male...😢


It became worse that I started begging my mates to sleep with me whenever the urge comes😭


I did several abortion and that never stopped me from the path I ignorantly chose that unforgettable 14th day of February...😭


I thought I was enjoying myself but I never knew I was carving a live coffin for myself...😭


Mum, I laughed when I saw you on TV yesterday, speaking to young girls on sexual purity...

I wished you had said half of those words to me...😭


It wouldn't have caused you anything to take me out for a cup of ice cream back then, you and I, one- on -one...🤦‍♀


I would have cherished that moment for life😭😭


I know I'm inexcusable but mum, you didn't help me either...😭


I decided not to come home all these years even after my NYSC since I knew I may one day force my only brother to bed😭😭😭


I'm not asking you to pity me, I only write to tell you what your insensitivity has caused me...😢


I plead with you to please raise my little sister well...😭


Today is another February 14th...

Please don't ask where I am...😭😭😭

(at least I told you I'm working and I sent you a monthly allowance for your upkeep and you have never for once asked about the nature of my work...)


Let me stop here for I know you may have another community meeting or...

Greet my Brandy and Tessy.

Tell them I love them both and wished I'm at home with them...

Please tell them I have chosen a path of destruction and I need help (if there's any...)😭😭😭😭😭

But beg them not to follow my example...

Please forgive me for not telling you all these years🙇‍♀

I truly regretted every of my actions mum and I'm so sorry😭😭😭😭😭😭


I still love you mum and if I can change the hand of time, I would have chosen better😭😭😭


YOUR LOST DAUGHTER.


(To Be Continued...)

Thursday, 11 February 2021

"DON'T START...!"


'Everyone is doing it and besides, he loves only me...'🤔


'Its just a little kiss...why talking as if he's taken me to bed? I know him, he won't do that! He's different from other guys...'🙆‍♀️


'Its just a harmless hug! He promised he won't go beyond that...'🤦‍♀


'You don't know him...he can't hurt a fly! He will never force me to bed without my consent even if we are alone in a room...'🤣


'Sitting on a guy's lap is no big deal... He's my friend with no strings attached...'🙄


'That experience was a mistake. He didn't mean to do it and he has promised never to do that again...'😤


'I can tell him anything...I prefer discussing heart to- heart matters with my male friends than the female ones. They are more caring and concerned...'🏃‍♀


'I can sleep on the same bed with a female and nothing will happen...' 🤭


👆👆👆👆👆👆

My counsel for you dear single:👇👇👇

DON'T START...!


Don't start a journey you cannot finish!

Don't showcase your goods to a thief!

Don't walk on a dead -end tunnel!


Don't give him the cover for he will go for the rest!

If you give a hem, he will remove the dress leaving you in shame and regrets...

You'll wish with tears that you never met!


Right now he's fanning the flame of deceit and you're rejoicing...

Beware lest you cast your pearls in the swine with your eyes blindfold with what you call love... please DON'T START!


Don't sing a song of woe and destruction!

Don't beat the drum of sorrow, don't sell your destiny... don't start a journey of nothingness!


Let not your innocence be stolen...

Let not your beauty be rubbed with pomade of shame and disgrace!

You are more than money can buy!

Your price is far above rubies!


Hear His pleas in Songs of Solomon 3:5(MESSAGE BIBLE.) 👇


"Oh, let me warn you, sisters in Jerusalem,

by the gazelles, yes, by all the wild deer:

Don't excite love, don't stir it up, 

until the time is ripe—and you're ready."


👆

I understand your emotions may be playing some pranks but trust the One who put it in you and He'll help you put it under check.

Please DON'T START...! WAIT instead... and you'll bless God you did!

The world is waiting for your glorious testimony 🥰 please don't mess it.

"DON'T START...!"



#DON'TSTART1

#LOGEMwrites

#LOGEMmin.

Monday, 8 June 2020

BEAUTY TREATMENT 2


(CONTINUED. FROM BEAUTY TREATMENT 1)

I was shocked to my marrows when I got to the place and discovered that Hegai had actually given me the most luxurious apartment in the Harem.
Not only that, he also gave me 7 girls from the palace as personal maids to attend to all my needs!!!
This was beyond my imaginations, it's simply unbelievable!!!

As if that was not enough, I was treated with a great deal of care and caution...I couldn't eat anyhow, dress anyhow or speak anyhow (I wasn't permitted to grow wildly... eunuch Hegai saw to it that I ate nothing apart from the special menu he ordered for me and he was always there to remind me the reason for which I was brought to the palace...I was practically shut out from what seems like 'enjoyment' to others but as far as Hegai was concerned, they are frivolities that will shift my focus from the real thing for which I was brought to Shushan Palace -the throne!

I submitted totally to his moulding hands, trusting God in him that he is more experienced than I am...
Apart from the fact that Hegai has been trained in doing this, I believed that God is not wicked, No! He is ever loving and His thought towards me are of PEACE and not of EVIL to give me a GLORIOUS FUTURE!

GOD IS ever Faithful and I'm sure HE wouldn't have allowed me to be brought to the palace and into the hands of this particular eunuch if He doesn't have something important to bring out of it...
I trusted God and I obeyed every instructions without questioning Hegai's authority, I received every corrections with joy!

Hegai favoured me for the Beauty treatments...
And I need not forget that my Uncle had instructed me earlier before coming to the palace that I musn't tell anyone I'm a Jewess, as a result of this, it wasn't possible for anyone to trace my origin throughout my stay in the Harem. Even when the other virgins gossiped about me among themselves, they usually ends with '... no one even knows where she comes from...'

I must not forget to tell you that within a short time, the effect of the beauty treatment started reflecting on me in every aspect, making my skin to come out glowing and beautiful...I knew it was the result of my being separated from the rest, most especially because I was on a special diet different from what other virgins were feeding on...
I was growing to becoming the King's pride!!!💃💃💃💃

"I  need to let you know that even though my Uncle wasn't with me in the Harem, his words and instructions were always flooding my mind daily...
It's as If, I wore them inside my heart like a garment...(I learnt from him later that he came daily to the court of the Harem,  since they can't allow anyone to get into the main Harem, he would strolled to the court of the Harem to ask about my welfare...he never left me alone even when I couldn't see him, he was always there... every single day and I never knew it!).

The enduring months of treatments passed by slowly (seems like forever)...
 
The pain and discipline in the period of making that lasted for a whole year cannot (did I say cannot??? Infact, it CAN NEVER EVER...) be compared to the pain and sorrow that awaits any virgin who eventually ends in the hands of Shaashgaz, the eunuch in charge of another Harem meant for concubines... and there she will spend the rest of her life!

The thought of ending in the other Harem with eunuch Shaashgaz always sent cold shivers down the spines of all the virgins except mine... you wonder why???

 I had this strong confidence that I'm not meant for Shaashgaz harem! When I wake up each morning, I perceive the re-assuring voice of JEHOVAH deep down in my heart as I commune with Him in devotion that 'I AM MEANT FOR THE THRONE'!!!

Several days rolled into weeks and weeks into months with the news of virgins in large numbers, ending in Shaashgaz Harem!
I kept trusting in God and fed on nothing else aside the special menu ordered for me by Hegai...

My time to visit the King's Chamber eventually came...!

The fact that many in their hundreds or thousands had gone before me and had failed fairly or woefully didn't move me...

The wailing of the previous night by the last virgin before me, who failed to please the King didn't move me...

The fact that I didn't hear the gists of the latest walking steps from other virgins didn't move me...

That each of us have just a night to spend with the King did not move me either...

The only thing that moved my heart were the words of JEHOVAH spoken to me and displayed by the trainings of Hegai...they became the tune my heart sang to as I journeyed the path to my fulfilment according to God's purpose for my life...

(HEBREWS 12:11 👉👇
 For the time being no discipline brings joy, but seems grievous and painful; but afterwards it yields a peaceable fruit of righteousness to those who have been trained by it [a harvest of fruit which consists in righteousness--in conformity to God's will in purpose, thought, and action, resulting in right living and right standing with God.)
##BEAUTY TREATMENT2
##POTTER's HANDMAID